[eventchamp_content_title size=”size1″ title=”dark” align=”center” separator=”true” titleone=”” titletwo=”EGBA Anthem” description=”” icon=””]
Verse: Lori oke o’un petele Ibe l’agbe bi mi o, Ibe l’agbe to mi d’agba oo, Ile ominira
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
Verse: Abeokuta ilu Egba N ko ni gbagbe e re N o gbe o l’eke okan mi Bii ilu odo oya Emi o f’Abeokuta sogo N o duro l’ori Olumo; Maayo l’oruko Egba ooo Emi omoo Lisabi E e
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
Verse: Emi o maayo l’ori Olumo Emi o s’ogoo yi l’okan mi Wipe ilu olokiki o L’awa Egba n gbe
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo